Ile Oko lle-eko ni
Olootu, Oruko mi ni Olakunle Ayuba , mo se Igbeyawo pelu ololufe mi Omokehinde ni August odun 2025, ni ojo Igbeyawo yi Taiwo o je kin gbadun tosan toru ni tele mi kaakiri o ni wipe okunrin eyokan pere ni awon mejeeji fe fise omo , Sugbon Omokehinde ni emi fe fise Iyawo, nse ni awon mejeeji jo pawopo le mi lori wipe awon mejeeji ni awon fe jo maa gbe papo , Sugbon igbati awon parents won rii wipe oro naa ti fe da Igbeyawo omokehinde re , Esekese niwon bawon soro ti awon mejeeji si jawo wipe awon tigbo awon siti gba , Sugbon igbati o di ipari December odun 2025 ni awon mejeeji ba ni wipe doctor tiso fun awon wipe awon tini oyun , emi ni mo sini oyun awon mejeeji ,Oro yi toju sumi, bawo ni mo se maa fe Iyawo eyokan ti Iyawo meji maa wa ni oyun fun mi, Esekese ni Omokehinde Iyawo mi ni wipe awon jo ma pin oorun sun pelu Taiwo ni, omokehinde ni wipe awon mejeeji ni mo ma ba ni ere Ibalopo, o ni wipe awon ma pin oorun sun ni , sugbon emi o mo wipe plan won niyan , ni bayi awon mejeeji ti ni oyun fun mi , Omokehinde 4 months pregnant then Taiwo 3 months pregnant, awon mejeeji niwon jo arawon Opolopo awon eniyan niwon o mo Taiwo yato si kehinde ,Sugbon amin olorun tio wa ni ibi imun Omokehinde ti mo ma finda mo yato si kehinde , ase awon mejeeji ti lo dogbon fi amin black spot yan si imun Taiwo naa , Sugbon emi o ni agbara Iyawo meji arara , mio be olorun fun Iyawo meji ni ati kekere mi ni moti ma se adura yan, Sugbon nitori oro yi mo ti fi ile sile fun awon mejeeji kiwon ma se oko arawon, ojoojumo ni awon family nbe mi wipe kingba awon mejeeji papo wipe family mejeeji ma support mi financially, Sugbon awon omo yi feran sex bajebaje, gbogbo igba ni sex , Sugbon e mi ti so fun daddy mi wipe mo maa gba oyun Taiwo naa sugbon tio ba ti bi omo inu re tan kio maa lo , Olootu ejowo kini opinion yin lori oro yi , gbogbo ile Atejise timo ri gba ni ati odo Mr Olakunle Ayuba niyi oh , e gbo se ni tooto ni nkan yi le sele sa, iha wo ni asa ati ise Yoruba kosi iru oro yi , iha wo ni esin islam ko si iru oro bayi,, iha wo ni esin Christianity kosi iru nkan bayi, ejowo e baw tan imole si oro naa ki e si bawa fun Mr Olakunle Ayuba naa ni ni Imoran, ki e si bawa share re kio kari Aiye, ire oh
Where is it happening?
Iddo, Lagos, Nigeria
Know what’s Happening Next — before everyone else does.
Host or PublisherIle-Oko Ile-Eko Nio






